Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 17:23-24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

23. Èlíjà sì mú ọmọdé náà, ó sì gbé e sọ̀kalẹ̀ láti inú yàrá òkè náà wá sínú ilé. Ó sì fi lé ìyá rẹ̀ lọ́wọ́; Èlíjà sì wí pé, “Wò ó, ọmọ rẹ yè!”

24. Obìnrin náà sì wí fún Èlíjà pé, “Nísinsìnyìí mo mọ̀ pé ènìyàn Ọlọ́run ni ìwọ ń ṣe, àti pé òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ní ẹnu rẹ.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 17