Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 17:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èlíjà sì mú ọmọdé náà, ó sì gbé e sọ̀kalẹ̀ láti inú yàrá òkè náà wá sínú ilé. Ó sì fi lé ìyá rẹ̀ lọ́wọ́; Èlíjà sì wí pé, “Wò ó, ọmọ rẹ yè!”

Ka pipe ipin 1 Ọba 17

Wo 1 Ọba 17:23 ni o tọ