Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 10:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n ń mú kẹ̀kẹ́ kan gòkè láti Éjíbítì wá fún ẹgbẹ̀ta (600) ṣékélì fàdákà àti ẹsin kan fún àádọ́jọ (150). Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n tún mú wọn wá fún ọba àwọn ọmọ Hítì àti ọba àwọn ọmọ Árámánì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 10

Wo 1 Ọba 10:29 ni o tọ