Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 10:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì ní ọkọ̀ Tásísì kan pẹ̀lú ọkọ̀ Hírámù ní òkun. Ẹ̀ẹ̀kan ní ọdún mẹ́ta ni ọkọ̀ Tásísì ń dé, tí ó ń mú wúrà àti fàdákà, eyín-erin àti ìnàkí àti ẹyẹ-ológe wá.

Ka pipe ipin 1 Ọba 10

Wo 1 Ọba 10:22 ni o tọ