Nígbà tí ayaba Ṣébà gbọ́ òkìkí Sólómónì àti ìbáṣepọ̀ rẹ̀ níti orúkọ Olúwa, ó sì wá láti dán an wò pẹ̀lú ìbéèrè líle.