Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àdóníjà ẹni tí ìyá rẹ̀ ń ṣe Hágátì sì gbé ara rẹ̀ ga, ó sì wí pé, “Èmi yóò jẹ ọba.” Ó sì sètò kẹ̀kẹ́ ogun àti àwọn ẹlẹ́sin, pẹ̀lú àádọ́ta ọkùnrin láti máa sáré níwájú rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Ọba 1

Wo 1 Ọba 1:5 ni o tọ