Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 1:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

(Baba rẹ̀ kò bà á nínú jẹ́ rí nípa bíbéèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Èéṣe tí ìwọ fi hùwà báyìí?” Ó sì jẹ́ arẹwà ọkùnrin, òun ni a bí lé Ábúsálómù.)

Ka pipe ipin 1 Ọba 1

Wo 1 Ọba 1:6 ni o tọ