Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 1:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ènìyàn sì gòkè tọ̀ ọ́ lẹ́yìn wọ́n ń fọn ìpè, wọ́n sì ń yọ ayọ̀ ńlá, tó bẹ́ẹ̀ tí ilẹ̀ mì fún ìró wọn.

Ka pipe ipin 1 Ọba 1

Wo 1 Ọba 1:40 ni o tọ