Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 1:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sádókù àlùfáà sì mú ìwo òróró láti inú àgọ́, ó sì dà á sí Sólómónì lórí. Nígbà náà ni wọ́n sì fọn fèrè, gbogbo àwọn ènìyàn sì ké pé, “Kí Sólómónì ọba kí ó pẹ́!”

Ka pipe ipin 1 Ọba 1

Wo 1 Ọba 1:39 ni o tọ