Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 1:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àdóníjà àti gbogbo awọn àlejò tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ gbọ́ ọ́ bí wọ́n ti ń jẹun tán, wọ́n ń gbọ́ ipè, Jóábù sì wí pé, “Kí ní ìtumọ̀ gbogbo ariwo nínú ìlú yìí?”

Ka pipe ipin 1 Ọba 1

Wo 1 Ọba 1:41 ni o tọ