Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 26:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéríyà ní ẹgbàáméjì, àti ọgọ́rin méje ìbátan, tí wọn jẹ́ ọkùnrin alágbára àti olórí àwọn ìdilé ọba Dáfídì sì fi wọ́n ṣe àkóso lórí àwọn ará Reúbẹ́nì àwọn ará Gádì àti ààbọ̀ ẹ̀yà ti Mánásè fun gbogbo ọ̀rọ̀ tí ó jọ mọ́ ti Ọlọ́run àti fún ọ̀ràn ti ọba.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 26

Wo 1 Kíróníkà 26:32 ni o tọ