Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 26:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níti àwọn ará Hébírónì, Jéríyà jẹ́ olóyè wọn gẹ́gẹ́ bí ìwé ìrántí ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn ní ti ìdílé wọn. Ní ọdún kẹrin ìjọba Dáfídì, a ṣe ìwádìí nínú ìwé ìrántí, àwọn ọkùnrin alágbára láàrin àwọn ará Hébíronì ni a rí ní Jáṣérì ní Gílíádì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 26

Wo 1 Kíróníkà 26:31 ni o tọ