Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 22:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì wí pé, Ọmọ mi Sólómónì ọ̀dọ́mọdé ni ó sì jẹ́ aláìní ìríri, ilé tí a ó kọ́ fún Olúwa gbọdọ̀ jẹ́ títóbi jọjọ, kí ó sì ní òkìkí àti ògo jákèjádò gbogbo àwọn orílẹ̀ èdè. Nítorí náà ni èmi yóò ṣe pèsè sílẹ̀ fún un. Bẹ́ẹ̀ ni Dáfídì sì ṣe ìpèsè sílẹ̀ lọ́pọ̀lọpọ̀ kí ó tó di wí pé ó kú.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 22

Wo 1 Kíróníkà 22:5 ni o tọ