Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 21:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Órínánì ni ó sọ fún Dáfídì pé, “Gbà á! Jẹ́ kí Olúwa ọba mi kí ó ṣe ohun tí ó dára lójú Rẹ̀. Woó, èmí yóò fún ọ ní àwọn màlúù fún ẹbọ ọrẹ ṣiṣun, àti ohun èlò ìpakà fún igi, àti ọkà fún ọrẹ oúnjẹ. Èmi yóò fun ọ ní gbogbo èyí.”

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 21

Wo 1 Kíróníkà 21:23 ni o tọ