Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 21:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì wí fún un pé, “Jẹ́ kí èmi kí ó ni ibi ìpakà rẹ kí èmi kí ó sì lè kọ́ pẹpẹ fún Olúwa, kí àjàkálẹ̀-àrùn lórí àwọn ènìyàn lè dúró. Tàá fún mi ní iye owó kíkún.”

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 21

Wo 1 Kíróníkà 21:22 ni o tọ