Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 18:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fi Gárísónì sí Édómù, gbogbo àwọn ará Édómù sì ń sìn ní abẹ́ Dáfídì. Olúwa fún Dáfídì ní ìṣẹ́gun ní gbogbo ibí tí ó bá lọ.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 18

Wo 1 Kíróníkà 18:13 ni o tọ