Láti ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni òkúta igun ilé ti jáde wá,láti ọ̀dọ̀ rẹ ni igi-èèkàn àgọ́ tí wá,láti ọ̀dọ̀ rẹ ni ọrún ogun tí wá,láti ọ̀dọ̀ rẹ ni àwọn akóniṣiṣẹ́ gbogbo tí wá.