Mósè ìránṣẹ́ Olúwa àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì borí wọn. Mósè ìránṣẹ́ Olúwa sì fi ilẹ̀ wọn fún àwọn ẹ̀yà Rúbẹ́nì, àwọn ẹ̀yà Gádì àti ìdajì ẹ̀yà Mánásè kí ó jẹ́ ohun ìní wọn.