Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 12:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ̀nyí ní àwọn ọba ilẹ̀ náà tí Jóṣúà àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sẹ́gun ní ìhà ìwọ̀-oòrùn Jọ́dánì, láti Báálì Gádì ní Àfonífojì Lẹ́bánónì sí Okè Hálákì, èyí tí O lọ sí ọ̀nà Sérì (Jóṣúà sì fi ilẹ̀ wọn fún àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì ní ilẹ̀ ìní gẹ́gẹ́ bí ìpín ẹ̀yà wọn:

Ka pipe ipin Jóṣúà 12

Wo Jóṣúà 12:7 ni o tọ