Ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó tọ Hósíà ọmọ Béérì wá ní àkókò ìjọba Ùsáyà, Jótamù, Áhásì àti Heṣekáyà; àwọn ọba Júdà àti ní àkókò ọba Jéróbóámù ọmọ Jóásì ní Ísírẹ́lì: