Gbogbo ẹwà ti di ohun ìgbàgbé.Àwọn ọmọ ọba kùnrin dàbí i ìgalàtí kò rí ewé tútù jẹ;nínú àárẹ̀ wọ́n sáréníwájú ẹni tí ó ń lé wọn.