Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Aninilára rẹ̀ gbogbo di olúwa rẹ̀,nǹkan sì rọrùn fún àwọn ọ̀tá rẹ̀, Olúwa ti fún un ní ìjìyà tó tọ́nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.Àwọn ẹ̀ṣọ́ wẹ́wẹ́ rẹ̀ lọ sí oko ẹrú,ìgbèkùn níwájú àwọn ọ̀tá.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 1

Wo Ẹkún Jeremáyà 1:5 ni o tọ