Nígbà náà ni àwọn arọ yóò máa fò bí àgbọ̀nrín,àti ahọ́n odi yóò ké fún ayọ̀.Odò yóò tú jáde nínú ihààti àwọn odò nínú aṣálẹ̀.