Ẹ wá a nínú ìwé Olúwa, ẹ sì kà á:Ọ̀kan nínú wọ̀nyí kì yóò yẹ̀,kò sí ọ̀kan tí yóò fẹ́ ìkejìi rẹ̀ kù:nítorí Olúwa ti pàṣẹẹnu rẹ̀ ló sì fi kó wọn jọẸ̀mí rẹ̀ ló sì fi tò wọ́n jọ.