Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 27:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Pilatu ri pe, on ko le bori li ohunkohun, ṣugbọn pe a kuku sọ gbogbo rẹ̀ di ariwo, o bu omi, o si wẹ̀ ọwọ́ rẹ̀ li oju ijọ, o wipe, Ọrùn mi mọ́ kuro ninu ẹ̀jẹ enia olõtọ yi: ẹ mã bojuto o.

Ka pipe ipin Mat 27

Wo Mat 27:24 ni o tọ