Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 27:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bãlẹ si bère wipe, Ẽṣe, buburu kili o ṣe? Ṣugbọn nwọn kigbe soke si i pe, Ki a kàn a mọ agbelebu.

Ka pipe ipin Mat 27

Wo Mat 27:23 ni o tọ