Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 1:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni gbogbo iran lati Abrahamu wá de Dafidi jẹ iran mẹrinla; ati lati Dafidi wá de ikolọ si Babiloni jẹ iran mẹrinla; ati lati igba ikólọ si Babiloni de igba Kristi o jẹ iran mẹrinla.

Ka pipe ipin Mat 1

Wo Mat 1:17 ni o tọ