Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 2:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Jesu gbọ́, o wi fun wọn pe, Awọn ti ara wọn le kì iwá oniṣegun, bikoṣe awọn ti ara wọn ko da: Emi ko wá lati pè awọn olododo, bikoṣe awọn ẹlẹṣẹ si ironupiwada.

Ka pipe ipin Mak 2

Wo Mak 2:17 ni o tọ