Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 2:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn akọwe ati awọn Farisi si ri i ti o mbá awọn agbowode ati awọn ẹlẹṣẹ jẹun, nwọn wi fun awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ pe, Ẽtiri ti o fi mba awọn agbowode ati awọn ẹlẹṣẹ jẹ, ti o si mba wọn mu?

Ka pipe ipin Mak 2

Wo Mak 2:16 ni o tọ