Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 13:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nigbati nwọn ba nfà nyin, lọ, ti nwọn ba si nfi nyin le wọn lọwọ, ẹ maṣe ṣaniyan ṣaju ohun ti ẹ o sọ; ṣugbọn ohun ti a ba fifun nyin ni wakati na, on ni ki ẹnyin ki o wi: nitori kì iṣe ẹnyin ni nwi, bikoṣe Ẹmí Mimọ́.

Ka pipe ipin Mak 13

Wo Mak 13:11 ni o tọ