Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 11:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati ẹnyin ba si duro ngbadura, ẹ darijì, bi ẹnyin ba ni ohunkohun si ẹnikẹni: ki Baba nyin ti mbẹ li ọrun ba le dari ẹṣẹ nyin jì nyin pẹlu.

Ka pipe ipin Mak 11

Wo Mak 11:25 ni o tọ