Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 10:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wipe, Sá wo o, awa ngoke lọ si Jerusalemu, a o si fi Ọmọ-enia le awọn olori alufa, ati awọn akọwe lọwọ; nwọn o si da a lẹbi ikú, nwọn o si fi i le awọn Keferi lọwọ:

Ka pipe ipin Mak 10

Wo Mak 10:33 ni o tọ