Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 10:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si wà li ọ̀na nwọn ngoke lọ si Jerusalemu; Jesu si nlọ niwaju wọn: ẹnu si yà wọn; bi nwọn si ti ntọ̀ ọ lẹhin, ẹ̀ru ba wọn. O si tun mu awọn mejila, o bẹ̀rẹ si isọ gbogbo ohun ti a o ṣe si i fun wọn,

Ka pipe ipin Mak 10

Wo Mak 10:32 ni o tọ