Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kol 1:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si jẹ ori fun ara, eyini ni ìjọ: ẹniti iṣe ipilẹṣẹ, akọbi lati inu okú wá; pe, ninu ohun gbogbo ki on ki o le ni ipò ti o ga julọ.

Ka pipe ipin Kol 1

Wo Kol 1:18 ni o tọ