Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 4:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ẹnikẹni ti o ba mu ninu omi ti emi o fifun u, orùngbẹ kì yio gbẹ ẹ mọ́ lai; ṣugbọn omi ti emi o fifun u yio di kanga omi ninu rẹ̀, ti yio ma sun si ìye ainipẹkun.

Ka pipe ipin Joh 4

Wo Joh 4:14 ni o tọ