Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 15:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ ranti ọ̀rọ ti mo ti sọ fun nyin pe, Ọmọ-ọdọ kò tobi jù oluwa rẹ̀ lọ. Bi nwọn ba ti ṣe inunibini si mi, nwọn ó ṣe inunibini si nyin pẹlu: bi nwọn ba ti pa ọ̀rọ mi mọ́, nwọn ó si pa ti nyin mọ́ pẹlu.

Ka pipe ipin Joh 15

Wo Joh 15:20 ni o tọ