Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 15:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ibaṣepe ẹnyin iṣe ti aiye, aiye iba fẹ awọn tirẹ̀; ṣugbọn nitoriti ẹnyin kì iṣe ti aiye, ṣugbọn emi ti yàn nyin kuro ninu aiye, nitori eyi li aiye ṣe korira nyin.

Ka pipe ipin Joh 15

Wo Joh 15:19 ni o tọ