Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 12:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati ẹnyin ni imọlẹ, ẹ gbà imọlẹ gbọ́, ki ẹ le jẹ ọmọ imọlẹ. Nkan wọnyi ni Jesu sọ, o si jade lọ, o fi ara pamọ́ fun wọn.

Ka pipe ipin Joh 12

Wo Joh 12:36 ni o tọ