Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 12:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Jesu wi fun wọn pe, Nigba diẹ si i ni imọlẹ wà lãrin nyin. Ẹ mã rìn nigbati ẹnyin ni imọlẹ, ki òkunkun máṣe ba le nyin: ẹniti o ba si nrìn li òkunkun kò mọ̀ ibiti on gbé nlọ.

Ka pipe ipin Joh 12

Wo Joh 12:35 ni o tọ