Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Tes 3:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awa si paṣẹ fun nyin, ará, li orukọ Jesu Kristi Oluwa wa, ki ẹnyin ki o yẹra kuro lọdọ olukuluku arakunrin, ti nrin ségesège, ti kì iṣe gẹgẹ bi ìlana ti nwọn ti gbà lọwọ wa.

Ka pipe ipin 2. Tes 3

Wo 2. Tes 3:6 ni o tọ