Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kor 9:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhin ti nwọn fi iṣẹ-isin yi dan nyin wo, nwọn yin Ọlọrun li ogo fun itẹriba ijẹwọ́ nyin si ihinrere Kristi, ati fun ilàwọ ìdawó nyin fun wọn ati fun gbogbo enia;

Ka pipe ipin 2. Kor 9

Wo 2. Kor 9:13 ni o tọ