Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kor 12:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi mọ̀ ọkunrin kan ninu Kristi ni ọdún mẹrinla sẹhin, (yala ninu ara ni, emi kò mọ̀; tabi lati ara kuro ni, emi kò mọ̀; Ọlọrun ni o mọ): a gbé irú enia bẹ̃ lọ si ọ̀run kẹta.

Ka pipe ipin 2. Kor 12

Wo 2. Kor 12:2 ni o tọ