Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kor 1:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti ntù wa ninu ni gbogbo wahalà wa, nipa itunu na ti a fi ntù awa tikarawa ninu lati ọdọ Ọlọrun wá, ki awa ki o le mã tù awọn ti o wà ninu wahala-ki-wahala ninu.

Ka pipe ipin 2. Kor 1

Wo 2. Kor 1:4 ni o tọ