Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 4:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si pè wọn, nwọn paṣẹ fun wọn, ki nwọn máṣe sọ̀rọ rara, bẹni ki nwọn máṣe kọ́ni li orukọ Jesu mọ́.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 4

Wo Iṣe Apo 4:18 ni o tọ