Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 4:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ki o má bà tàn kalẹ siwaju mọ́ lãrin awọn enia, ẹ jẹ ki a kìlọ fun wọn pe, lati isisiyi lọ ki nwọn ki o máṣe fi orukọ yi sọ̀rọ fun ẹnikẹni mọ́.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 4

Wo Iṣe Apo 4:17 ni o tọ