Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 22:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati a si ta ẹ̀jẹ Stefanu ẹlẹri rẹ silẹ, emi na pẹlu duro nibẹ̀, mo si li ohùn si ikú rẹ̀, mo si nṣe itọju aṣọ awọn ẹniti o pa a.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 22

Wo Iṣe Apo 22:20 ni o tọ