Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 21:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn niti awọn Keferi ti o gbagbọ́, awa ti kọwe, a si ti pinnu rẹ̀ pe, ki nwọn pa ara wọn mọ kuro ninu ohun ti a fi rubọ si oriṣa, ati ẹ̀jẹ ati ohun ilọlọrùnpa, ati àgbere.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 21

Wo Iṣe Apo 21:25 ni o tọ