Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 21:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ni ki iwọ ki o mu, ki o si ṣe iwẹnumọ pẹlu wọn ki o si ṣe inawo wọn, ki nwọn ki o le fá ori wọn: gbogbo enia yio si mọ̀ pe, kò si otitọ kan ninu ohun ti nwọn gbọ si ọ; ṣugbọn pe, iwọ tikararẹ nrìn dede pẹlu, iwọ si npa ofin mọ́.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 21

Wo Iṣe Apo 21:24 ni o tọ