Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Tes 5:16-20 Yorùbá Bibeli (YCE)

16. Ẹ mã yọ̀ nigbagbogbo.

17. Ẹ mã gbadura li aisimi.

18. Ẹ mã dupẹ ninu ohun gbogbo: nitori eyi ni ifẹ Ọlọrun ninu Kristi Jesu fun nyin.

19. Ẹ máṣe pa iná Ẹmí.

20. Ẹ máṣe kẹgan isọtẹlẹ.

Ka pipe ipin 1. Tes 5