Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 7:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi ẹnikan ba rò pe on kò ṣe ohun ti o yẹ si wundia ọmọbinrin rẹ̀, bi o ba ti di obinrin, bi o ba si tọ bẹ̃, jẹ ki o ṣe bi o ti fẹ, on kò dẹṣẹ: jẹ ki nwọn gbé iyawo.

Ka pipe ipin 1. Kor 7

Wo 1. Kor 7:36 ni o tọ